Okan Bale

by Angélique Kidjo

From the album: Black Ivory Soul

Track 9 of 12 on Black Ivory Soul (2002).

Duration: 3:34

Black Ivory Soul cover art

Lyrics for Okan Bale

Okan bale o Okan bale o Okan bale o Okan bale o Emi ni kan ko ló wa la yé Omo dada lé mi Moni ebí pupó Momo gbogbó ibí témi laye Iri si dada ni témi e gbo o Momo pe éfe ran mí, éje ki n mo Dupé fun yin Ife yin fun mi layo Mo fe ki aye temi ko da Iya mi o, pélú baba mí (baba mí) Awon aburo mi n ko? (Baba mí) Mo n de dupé fun olúwa o (baba mí) To fun mí lébí tóda yi (baba mi) Mo n dupe fun ayé yí o Ododún maré mo n dupe Okan bale o Okan bale o Eni ti o ba nífe ninu ayé Pelú ebí dada óluwaré ajiya Gbogbo wa ninu aya wa ifé Kadúpe ti awa ba ri ife dada Momo pe éfe ran mí, éje ki n mo Dupé fun yin Ife yin fun mi layo, mo fe ki aye temi ko da Iya mi o, pélú baba mí (baba mí) Awon aburo mi n ko? (Baba mí) Mo n de dupé fun olúwa o (baba mí) To fun mí lébí tóda yi (baba mi) Modupe fun ayé yí o Ododún maré mo n dupe

Listen On

More from Black Ivory Soul

  1. Bahia
  2. Iwoya (feat. Dave Matthews)
  3. Olofoofo
  4. Tumba
  5. Black Ivory Soul
  6. Refavela
  7. Iemanja
  8. Afirika
  9. Okan Bale
  10. Ominira
  11. Mondjuba
  12. Ces Petits Riens